Ojú àmúwayé Akinwùmí Is̩ò̩lá àti Adébáyò̩ Fálétí nípa imúnisìn nínú eré-onítàn Abé̩ Aàbò àti Ìdààmú Páàdì Mínkáilù ní ìlànà tíórì As̩àtakò ìmúnisìn
| dc.contributor.author | Hamzat, S. A. O. | |
| dc.date.accessioned | 2025-05-07T11:35:38Z | |
| dc.date.available | 2025-05-07T11:35:38Z | |
| dc.date.issued | 2025 | |
| dc.description | Journal | |
| dc.description.abstract | Ìgbà lașo, ìgbà lewù, ìgbà lòdèré kókò nílé Ilorin. Kókó òrò igbà ò șé yọ kúrò ní ìgbésí ayé omọ ệdá. Àwón onísé onà àtinúdá ni wón dúró bí agbenuso fún egbé àti ogbà wọn ní àkókò kòòkan. Ídí niyí tí ìtúpalệ lítíréso fi wúlò fún àgbéyewò ìrírí ti ìsele àsikò kookan. Ipò àti ipa oníkálukú ni yóo sọ ìhà tí wọn yóò kọ sí ișèlệ àwùjọ yòówù tí wọn bá yàn láàyò. Èròǹgbà wa nínú pépà yìí ni láti fi tíórì asàtakò ìmúnisìn, abala tó jẹ mó àșà ìbílệ tú èrò báyéserí àwon ònkowé ìwé-eré onítàn Yorùbá nípa ìmúnisìn òyìnbó àti ipa r lórí èrò àti ișe àwon elésìn nínú ìwé-eré onítàn ajemésìn, Abé Aàbò àti Idààmú Páàdi Mínkáilù. A fi àbùdá ìmúnisìn àti ọ̀nà àbáyọ tí àwọn òǹkọ̀wé yìí dá ní àbá hàn. Àbájáde itúpalệ yìí fi hàn pé àwọn òyìnbó ni amúnisìn ìta tí ó fi ệyìn sílệ fún amúnisìn abélé tí ìmunisìn sì ń tệ síwájú. Àwọn ète tí wọn ń lò ni ệsìn àti ệkó. Àwọn ònkowé yìí șe àtèrì àșà òyìnbó nípa lílajú àwùjọ sí addàmodì ệkó esìn ní àwùjo abínibí, wón sì fi hàn pé kí a tẹra mó ìgbélárugę àșà àti èdè Yorùbá, pelú ìlòdì sí ti oyìnbó kí ìdàgbàsókè lè wà. Ișé yìí pè fún àmúlò tíọ́rì așàtakò ìmúnisìn ní gbogbo ẹ̀ka ìmọ̀ láti mú wa yí ojú àbùkù tí a fì n wo àșà àti ìșe abínibí padà lọ́nà tí ó lè mú ìdàgbàsókè bá àwùjọ òde òní. | |
| dc.description.sponsorship | Self | |
| dc.identifier.citation | Hamzat, S. A. O. (2025). Ojú àmúwayé Akinwùmí Is̩ò̩lá àti Adébáyò̩ Fálétí nípa imúnisìn nínú eré-onítàn Abé̩ Aàbò àti Ìdààmú Páàdì Mínkáilù ní ìlànà tíórì As̩àtakò ìmúnisìn. ALÓRE: Iorin Journal of the Humanities, 34, 177-189, Published by Faculty of Arts University of Ilorin. ISSN 0794-4551 | |
| dc.identifier.issn | 0794-4551 | |
| dc.identifier.uri | https://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/16337 | |
| dc.language.iso | en | |
| dc.publisher | Faculty of Arts University of Ilorin | |
| dc.title | Ojú àmúwayé Akinwùmí Is̩ò̩lá àti Adébáyò̩ Fálétí nípa imúnisìn nínú eré-onítàn Abé̩ Aàbò àti Ìdààmú Páàdì Mínkáilù ní ìlànà tíórì As̩àtakò ìmúnisìn | |
| dc.type | Article |
