Àyẹ̀wò ìbáyému nìnù o̩mo̩ olókùn ẹṣin àti ayé dayé òyìnbó YORÙBÁ GBÒDE
Loading...
Date
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
The Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo
DOI
Abstract
Àkíyèsí àyíká eni ló bí ìrírí eni. Ìrírí ònkowé ní yíká re ni yóò șe okùnfà irú ìtàn tí ònkowé le kọ. Orísirísi ònà ni àwon òùkòwé Yorùbá n gbà ko ìtàn àròso. A ti rí ìtàn òtelèmúyé, èyí tó dá lé ìtàn gidi àti èyí tó ń fi èhónú hàn sí ètò òṣèlú tàbí ohun tí ń lọ ní àwùjo. Èyí tí isé yìí dá lé ni ìtàn àròso tó dá lérí ìtàn gidi to ti selệ rí. Lára ohun tí irú àwọn ìwé yìí máa ń dá lé ni ìgbésí ayé àwon baba ńlá wa, ètò ìșèlú ayé ojóun, bí àwọn ìjòyè àti ológun șe ń darí ìlú, tí wọn ń jayé ta-ní-o-mú-mi tí àwọn mèkúnnù sì ń jìyà. Irú ìtàn àròsọ báyìí tún máa ń la ònà tí àwon ènìyàn, fi le jàjàgbara kúrò nínú ìgbèkùn sílệ nínú èyí tí wọn ó ti mú lyípadà dé bá asà wa. Culdre
Àwọn ònkòwé tó ti kọ irú ìtàn yìí ni Olóyè I.O. Délànò tó kọ Lojo Qjoun àti Ayé Dayé Òyìnbó; Adébáyò Fálétí tó kọ Ọmọ Olókùn Esin àti Basòrun Gáà; Akínwùmí Isòlá sì ko Efúnsetán Aníwúrà.
Description
Journal
Keywords
Citation
Hamzat, S. A. O. (2000). Àyẹ̀wò ìbáyému nìnù o̩mo̩ olókùn ẹṣin àti ayé dayé òyìnbó YORÙBÁ GBÒDE: Jọ́nà Ẹgbẹ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá, Nàìjíríà. 2 (3), 151-158, Published by the Association of the Teachers of Yorùbá Language, Department of African Languages and Literatures, Lagos State University, Ojo. ISSN; 1118-2482.