Jíjábọ̀ ìwádìí
Loading...
Date
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Department of Linguistics and Nigerian Languages, University of Ilorin, Ilorin.
DOI
Abstract
Ìfáàrà
Ó șe kókó láti mò ohun tí ó ń jẹ́ ìwàdí kí a le mọ pàtàkì àbò ìwádíì jíjé. Gbogbo ìgbésí ayé omo èdá ni ó kún fún àìyé. Àìyé ni ayé fúnra rệ, ohun tí kò yéni, tí a fệ kí aráyé gbó kí ó le șe àwọn ènìyàn tí òrò kàn ní ànfààní ni a ń șe ìwàdí lé lórí., torí náà ìmộ tuntun tí a fi bọ ayé ni. Èrò, òrò tàbí ișé tuntun kan la fẹ́ tà fáyé. Gbogbo ệka ìmò ló ní òfin àti ètò tí ó de ìlànà ìsewadìí, bákan náà ni ìlànà ìjábò gùn lé àwon òté kan. Bí èdè ìwádìí se yàto náà ni èdè ìjábo ìwádìí náà yàto sí èdè gbèfệ. Èròngbà wa ní orí yìí ni láti e àkóyawó àlàyé nípa òfin àti ààtò ìjàbò ìwádìí iș àkànse fún gbígba oyè tàbí ìwé ệrí Bí eè, ni Ệka Ìmộ dá Èdè àti Èdè Nàìjíríà, ní pàtàkì jùlo, ìlànà àti ètò ìjábo ìwádìí ìmo àșà, lítíréșò àti èdè Yorùbá. Ètò tí a tệlé nínú àpilệko yìí ni șíse àlàyé kókó òrò tí ò kan așèwádìí, pípe àkíyèsí won sí ojúse won àti àwon àșìse tí ó wóp láàárin àwọn akékòó, àlàyé àti afihàn ètò ișé láti èèpo yìn dé ìparí
àpilèko sì tèlé e.
Description
Home Based (Journal)
Keywords
Citation
. Hamzat, S. A. O. (2016). Jíjábọ̀ ìwádìí. In Ọgbọ́n Ìṣèwádìí Nínú Ìmọ̀ Ẹ̀dá Èdè, Lítíréṣọ̀ àti Àṣà Yorùbá. Adéye̩mí, L., Adéo͎s͎un, H. O., Adekeye, F. B. & O͎mo͎léwu, O. C. (eds.), 84-98. Published by Department of Linguistics and Nigerian Languages, University of Ilorin, Ilorin. ISBN; 978-978-952-978-0