<link rel="stylesheet" href="styles.f3b1fba60ec7970c.css">

Ifoju tiori Asa Ibile se Atupale Eto Igbeyawo ati Isomoloruko fun Alafin Oyo

Loading...
Thumbnail Image

Date

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Department of Linguistics and Languages, Adekunle Ajasin University

DOI

Abstract

O ̣̀kan lára ohun a wáyé wá ṣe ni ètò ìgbéyàwó àti ọmọ bíbí je ̣̀ níle ̣̀ Yorùbá. Ìdí sì nìyí tí wo ̣̀n fi máa ń sọ pé “Ẹní wáyé tí ò bímọ wáyé asán”. Iṣe ̣̀ yìí ṣe àtúpale ̣̀ àṣà ìgbéyàwó àti ìsọmọlórúko ̣̀ bí a t ií ṣe é láàfin O ̣̀yọ̀ láti ìgbà ìwáṣè títí di òní. Àwọn àṣà Yorùbá lo ̣̀kan-ò-jọ̀ kan ló ti ń dohun ìgbàgbé látàrí àìní àǹfààní láti gán-án-ni bí a ṣe n. ṣe wo ̣̀n láto ̣̀do ̣̀ àwọn àgbà. Èròńgbà iṣẹ̀ yìí ni láti wá ojútùú sí ìṣoro yìí níwọ̀ nba ìgbà tó je ̣̀ pé ó ṣòro fún ake ̣̀ko ̣̀o ̣̀ láti kù gììri wọ inú ààfin O ̣̀yọ̀ fún iṣe ̣̀ ìwádìí. Ìdi gan-an sì rèé tí a fi lo ọgbọ̀ ìso ̣̀tàn ‘ó-s.ojú-ù-mi-kòró láti le lo ìrírí òǹko ̣̀wé yìí ge/̣̀ge ̣̀ bí Ayaba. Tío ̣̀rì sosio ̣̀lo ̣̀jí lítíréṣo ̣̀ ni yóò ràn wá lo ̣̀wo ̣̀ dáadáa láti le ṣe àtúpale ̣̀ ọ̀ hún dójú àmì. Àbọ̀ ìwádìí je ̣̀ ká rí ètò ìgbéyàwó àti ìsọmọlórúkọ láàfin O ̣̀yọ̀ lo ̣̀nà tí ó yàto ̣̀ sí ti gbogbogbòò níle ̣̀ Yorùbá. Ise ̣̀ yìí dá a lábàá kí á túnbo ̣̀ ṣe àwárí àwón àṣà àti ìṣe Yorùbá pàápàá nínú ààfin àwọn ọba kí á sì ṣe àfíwéra re ̣̀ pẹ̀ lúu tòde òní nírètí àti to ̣̀jú àwòn ohun wo ̣̀n-ọn-nì kí ó má baà di ohun ìgbàgbé torí tí ọmọdé ò bá bá ìtàn, o dáa kí ó bá àro ̣̀bá tíi ṣe baba ìtàn.

Description

Citation

Collections

Endorsement

Review

Supplemented By

Referenced By