<link rel="stylesheet" href="styles.f3b1fba60ec7970c.css">

The significance of Yorùbá oral poetry in language acquisition In Islamics, Scholarship and Service to Humanity: A Festschrift in Honour of Prof. Is-haq Olanrewaju Oloyede.

dc.contributor.authorAdéigbe I. A.
dc.contributor.authorHamzat S. A. O.
dc.date.accessioned2025-05-07T09:59:57Z
dc.date.available2025-05-07T09:59:57Z
dc.date.issued2024
dc.descriptionChapters in Book
dc.description.abstractÓ șe kókó láti mò ohun tí ó ń jẹ́ ìwàdí kí a le mọ pàtàkì àbò ìwádíì jíjé. Gbogbo ìgbésí ayé omo èdá ni ó kún fún àìyé. Àìyé ni ayé fúnra rệ, ohun tí kò yéni, tí a fệ kí aráyé gbó kí ó le șe àwọn ènìyàn tí òrò kàn ní ànfààní ni a ń șe ìwàdí lé lórí., torí náà ìmộ tuntun tí a fi bọ ayé ni. Èrò, òrò tàbí ișé tuntun kan la fẹ́ tà fáyé. Gbogbo ệka ìmò ló ní òfin àti ètò tí ó de ìlànà ìsewadìí, bákan náà ni ìlànà ìjábò gùn lé àwon òté kan. Bí èdè ìwádìí se yàto náà ni èdè ìjábo ìwádìí náà yàto sí èdè gbèfệ. Èròngbà wa ní orí yìí ni láti e àkóyawó àlàyé nípa òfin àti ààtò ìjàbò ìwádìí iș àkànse fún gbígba oyè tàbí ìwé ệrí Bí eè, ni Ệka Ìmộ dá Èdè àti Èdè Nàìjíríà, ní pàtàkì jùlo, ìlànà àti ètò ìjábo ìwádìí ìmo àșà, lítíréșò àti èdè Yorùbá. Ètò tí a tệlé nínú àpilệko yìí ni șíse àlàyé kókó òrò tí ò kan așèwádìí, pípe àkíyèsí won sí ojúse won àti àwon àșìse tí ó wóp láàárin àwọn akékòó, àlàyé àti afihàn ètò ișé láti èèpo yìn dé ìparí àpilèko sì tèlé e.
dc.description.sponsorshipSelf
dc.identifier.citationAdéigbe I. A. & Hamzat S. A. O. (2024). The significance of Yorùbá oral poetry in language acquisition In Islamics, Scholarship and Service to Humanity: A Festschrift in Honour of Prof. Is-haq Olanrewaju Oloyede. Adedimeji A. & AbdulGafar O. Fahm (eds.), 155-164. Published by The Consortium of Universities in Kwara State (KU8+) University of Ilorin, Ilorin, Nigeria. ISBN; 978-978-61001-1-1.
dc.identifier.isbn978-978-61001-1-1
dc.identifier.urihttps://uilspace.unilorin.edu.ng/handle/123456789/16211
dc.language.isoen
dc.publisherThe Consortium of Universities in Kwara State (KU8+) University of Ilorin, Ilorin, Nigeria.
dc.titleThe significance of Yorùbá oral poetry in language acquisition In Islamics, Scholarship and Service to Humanity: A Festschrift in Honour of Prof. Is-haq Olanrewaju Oloyede.
dc.typeBook chapter

Files

Original bundle

Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
5_local_Oloyede_merged.pdf
Size:
45.96 MB
Format:
Adobe Portable Document Format

License bundle

Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections